Zaynab Alkali
Ìrísí
Zaynab Alkali | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 1950 Tura-Wazila, Ìpínlè Borno[1] |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹ̀kọ́ | Yunifásitì Bayero ti Kano |
Gbajúmọ̀ fún | first woman novelist from Northern Nigeria |
Olólùfẹ́ | Mohammed Nur Alkali |
Àwọn ọmọ | Àwọn ọmọ mẹ́fà |
Zaynab Alkali (tí a bí ní ọdún 1950) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n sínú ìdílé Tura-Mazila ní Ìpínlẹ̀ Bọ̀rnó.[2] Ó lọ ilé-ìwé Queen Elizabeth Secondary School ti ìlú Ilorin kí ó tó tẹ̀síwájú ní Yunifásítì Àmọ́dù Béllò (ABU), Zaria àti ní Yunifásítì Bayero ti Kano (BUK) láti gba àmì-ẹ̀yẹ Dokita(PhD) nínú ìmò Inglisi.[2]
Ìpìlẹ̀ àti Ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bí Alkali ní Tura-Wazila ní ìpínlẹ̀ Borno ní ọdun 1950. Ó kàwé gboyè ní Yunifásítì Báyéró ti ìpínlẹ̀ Kano pẹ̀lú àmì-ẹ̀yẹ BA ní ọdún 1973.[3] Ó gba àmì-ẹ̀yẹ Dókítá nínú ìmò nípa ilẹ̀ Áfríkà ní Yunifásitì kan náà kí ó tó padà di adarí ilé-ìwé Shekara Girls' Boarding School. Ó padà di olùkọ́ni nínú ìmọ̀ èdè Inglisi ní àwọn Yunifásitì méjì ní Nàìjíríà.[4]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Galleria, Nigeria. "Nigeria Personality Profile". Nigeria Galleria. Galleria Media Limited. Retrieved 11 March 2019.
- ↑ 2.0 2.1 Kabir, Hajara Muhammad (2010). Northern women development. Nigeria. ISBN 978-978-906-469-4. OCLC 890820657.
- ↑ Margaret Busby, Daughters of Africa, London: Cape, 1992, p. 782.
- ↑ Professor Henry Louis Gates, Jr.; Professor Emmanuel Akyeampong; Steven J. Niven (2 February 2012). Dictionary of African Biography. OUP USA. pp. 177–178. ISBN 978-0-19-538207-5. https://books.google.com/books?id=39JMAgAAQBAJ&pg=PA301.