Yusuf Lule
Ìrísí
Yusuf Lule | |
---|---|
4th President of Uganda | |
In office 13 April 1979 – 20 June 1979 | |
Asíwájú | Idi Amin |
Arọ́pò | Godfrey Binaisa |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Yusuf Kironde Lule 10 April 1912 Kampala, Uganda Protectorate |
Aláìsí | 21 January 1985 (aged 72) London, United Kingdom |
Yusuf Kironde Lule (10 April 1912 – 21 January 1985) fìgbà kan jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ti orílẹ̀-èdè Uganda, àti òṣìṣẹ́ ìjọba tó sìn gẹ́gẹ́ bí i ààrẹ Uganda kẹrin láàárín oṣù kẹrin àti oṣù kẹfà ọdún.
Ìgbésí ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Yusuf Lule ní 10 Aprilm ọdún 1912 ní Kampala.[1] Ó kàwé ní King's College Budo (1929–34), Makerere University College, Kampala, ní ọdún (1934–36), Fort Hare University ní Alice, South Africa (1936–39) àti ní University of Edinburgh.[2] Ẹlésìn Mùsùlùmí ni tẹ́lẹ̀ kí ó tó gbẹ̀sìn Kìrìsìtẹ́ẹ́nì nígbà tó wà ní King's College Budo.[3]
Ní ọdún 1947, Lule fẹ́ Hannah Namuli Wamala ní ilé-ìjọsìn Kings College Budo, níbi tí ó ti ṣiṣẹ́ bí i olùkọ́, tí arábìrin náà sì jẹ́ olórí àwọn obìnrin.[4]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Lule, K. Yusufu", Africa Who's Who, London: Africa Journal for Africa Books Ltd, 1981, p. 636.
- ↑ "Uncovering University of Edinburgh's black history". 30 April 2021. Archived from the original on 21 September 2023. Retrieved 27 July 2023.
- ↑ Mubangizi, Michael (11 January 2012). "They stand tall in new found faith". The Observer. Archived from the original on 15 August 2021. https://web.archive.org/web/20210815235417/https://observer.ug/lifestyle/sizzling-faith/16612-they-stand-tall-in-new-found-faith.
- ↑ Okech, Jennifer A. (5 June 2011). "Farewell to Hannah Namuli Lule". Daily Monitor. Retrieved 5 April 2020.