William Adams
Ìrísí
William Adams (1564-1620) | ||
Names: | ||
---|---|---|
Christian name: | William Adams | |
Japanese name: | Miura Anjin (三浦按針) | |
Dates: | ||
Birth: | Gillingham, Kent, England | Oṣù Kẹ̀sán 24, 1564|
Death: | May 16, 1620 Hirado, Kyūshū, Japan | (ọmọ ọdún 55)
William Adams Wọ́n bí Adams ní 1564. Ó kú ní 1620. Iṣẹ́ ọkọ̀ ojú omi (navigation) ni ó ń ṣe. Dillingham, Kent ni wọ́n ti bí i ní ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì. Òun ni ọmọ ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì àkọ́kọ́ tí yóò lọ sí Japan. Shogun Ieyasu ní ìfẹ́ sí i gidi ni, nítorí ìdí èyí, wọn fi ibi tí àwọn Gẹ̀ẹ́sì àti Dutch ti lè máa ṣòwò lélẹ̀ ní Japan. Eléyìí sì wà títí di 1616.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |