Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 4 Oṣù Kẹfà
Ìrísí
Ọjọ́ 4 Oṣù Kẹfà: Ọjọ́ Òmìnira ní Tonga (1970)
- 1943 – Ìfipágbàjọba ológun ní Argentina lé ìjọba Ramón Castillo kúrò.
- 1979 – Jerry Rawlings gba ìjọba ní Ghana lẹ́yìn ìfipágbàjọba ológun lọ́wọ́ Ọ̀gágun Fred Akuffo.
- 1989 – Ìwọ́de Ìta Tiananmen parí pẹ̀lu jàgídíjàgan ní Beijing látọwọ́ Jagunjagun ilẹ̀ Ṣáínà.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1907 – Jacques Roumain, olùkọ̀wé ará Haiti (al. 1944)
- 1915 – Modibo Keita, Ààrẹ àkọ́kọ́ ilẹ̀ Mali (al. 1977)
- 1968 – Al B. Sure!, akọrin ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1971 – Georg Lukács, amòye ará Hungari (ib. 1885)
- 1996 - Kudirat Abiola, alákitiyan òsèlú ará Naijiria (ib. 1951)