Ufuoma McDermott
Ufuoma McDermott | |
---|---|
Ufuoma Ejenobor at a photo shoot in 2008 | |
Ọjọ́ìbí | Ufuoma Stacey Ejenobor 23 Oṣù Kẹrin 1981 Benin City, Edo, Nigeria |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Yunifásítì ìlú Èkó |
Iṣẹ́ | Actor, Presenter, Producer, Film Director. |
Ìgbà iṣẹ́ | 2004–present |
Olólùfẹ́ | Steven McDermott (m. 2010) [1] |
Àwọn ọmọ | 2 |
Ufuoma Stacey McDermott (tí a bí ní 23 Oṣù Kẹẹ̀rin, Ọdún 1981)[2][3] jẹ́ òṣèrébìnrin, afẹwàṣiṣé, àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[4]
Ìbẹ̀rẹ̀ ayẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bí Ejenobor ní Ìlú Benin ṣùgbọ́n àwọn òbí rẹ̀ jẹ́ ẹ̀yà Urhobo tí ó wá láti Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà. Nígbà tí ó wà lọ́mọ ọdún mẹ́je, bàbá rẹ̀ fun ní orúkọ ìnagi tí n ṣe ISIO (èyítí ó túmọ̀ sí “oníràwọ̀” ní èdè Urhobo ). Wọ́n sọ orúkọ rẹ̀ láti fi jọ ti gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin kan tí ó maá n ṣe atọ́kùn ètò The Pot of Life lóri ìkànnì NTA Benin.
Ọ̀rọ̀ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ejenobor di aládélórí ní 23 Oṣù Kẹẹ̀rin Ọdún 2010 pẹ̀lú fífẹ́ Steven McDermott,[5] ṣùgbọ́n ó yí orúkọ rẹ̀ padà sí Ufuoma McDermott ní 23 Oṣù Kaàrún Ọdún 2014 ní ilé-ẹjọ́ gíga ti ìlú Èkó.[6]
Ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó lọ sí Alama Private School ní ìlú Jọs, ìpínlẹ̀ Plateau. Ó tún lọ sí Tunwase Nursery and primary school ní ìlú Ikeja, ní Ìpínlẹ̀ Èkó kí ó tó tún wá lọ sí Molly International Nursery and primary school ní Ajao Estate fún ètò-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀. Lẹ́hìn náà, ó lọ sí Federal Government College, Odogbolu, Ìpínlẹ̀ Ògùn fún ètò-ẹ̀kọ́ girama rẹ̀.
Ufuoma ti gba oyè nínu ìmọ̀ èdè Faransé láti Yunifásítì ìlú Èkó. Ó tún ní oyè gíga nínu ìmọ̀ Ọ̀rọ̀ Ìlú àti Káríayé láti Yunifásítì ìlú Èkó bákan náà.[7]
Ní ọdún 2011, ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga New York Film Academy tí ó wà ní ìlú Los Angeles láti kọ́ ẹ̀kọ́ eré ṣíṣe. Ní ọdún 2013, ó gba oyè nínu ìmọ̀ ìṣàkóso àwọn òṣìṣẹ́ láti London Business School.[8][9]
Iṣẹ́ ìṣe rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ìdárayá gẹ́gẹ́ bi afẹwàṣiṣẹ́ ní ọdún 2000 kí ó tó tún wá lọ fún ìdíje ẹwà.
Ìdíje ẹwà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọdún 2002, ó ti kópa nínu àwọn ìdíjẹ méji kan. Ó gbégbá orókè níbi ìdíje ẹwà Miss Ebony beauty pageant ṣùgbọ́n ó gba ẹ̀bùn ti Miss Congeniality níbi ìdíje ẹlẹ́kejì, ìyẹn ti Miss Commonwealth.
Eré sinimá àgbéléwò
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní Oṣù Kejì, Ọdún 2004, Ejenobor pinnu láti máa ṣiṣẹ́ fíìmù. Ó kọ́kọ́ kópa nínu eré Zeb Ejiro kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ The President Must Not Die. Ní Oṣù Kaàrún Ọdún 2005, ó kó àkọ́kọ́ ipa Olú-ẹ̀dá-ìtàn rẹ̀ nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Life and Death.
Ní ọdún 2008, ó kópa gẹ́gẹ́ bi “Lillian Wright” nínu eré tẹlifíṣònù tí àkọ́lé rẹ̀ n ṣe My Mum and I.[10][11][12]
Àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àmì-ẹ̀yẹ | Ẹ̀ka | Èsì |
---|---|---|---|
2003 | Nigerian French Village | Fille Africaine | Gbàá |
2007 | African heart foundation at The African Fashion show | Best Model | Gbàá |
2009 | African Youth Society | Role Model Award | Gbàá |
2010 | Golden Nymph Award at the Monte Carlo Television Festival | Best Actress in a comedy | Wọ́n yàán [13] |
2010 | Terracotta Television and Film Awards | Best Actress in a drama series | Wọ́n yàán [14] |
2011 | The Future Awards | Best Actress | Wọ́n yàán [15][16] |
2014 | AMVCA Africa Magic Viewers choice awards | Best New media-Online video | Wọ́n yàán (JUNGLE JEWEL) [17][18] |
2015 | Delta Entertainment Awards | Most Outstanding Actress | Gbàá[19][20] |
2016 | ELOY Awards | Actress (Big screen) | Wọ́n yàán [21][22][23][24] |
2017 | City People Awards | Best Actress | Gbàá |
Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Film | Role | Notes |
---|---|---|---|
2004 | The President Must Not Die | Detective- Supporting role | Film Director Zeb Ejiro starring Ibinabo Fiberesima, Enebeli Elebuwa- Released 2005 |
2004 | Life Partner | Film Director Adim Williams also starring Jim Iyke, Lilian Bach | |
2004 | Queen of My Heart | Claudia | Film Director Neville Ossai starring Rita Dominic, Clem Ohameze |
2004 | Secrets and Lies | TV mini-series | |
2005 | Life and Death | *1st Lead Role. Film Director Bond Emeruwa starring Zack Orji, Emeka Ossai | |
2005 | Guy on The Line | Film Director Jaja Michael starring Rita Dominic, Jim Iyke, Chidi Mokeme | |
2005 | Missed Love | Film Director Adim Williams starring Oge Okoye, Hank Anuku, Jim Iyke | |
2005 | Two Good Friends | Floxy | Film Directors Famous Otakpowen and Omoefe Kingsley starring John Okafor, Empress Njamah, Grace Amah, Uche Jombo |
2005 | Desperate Billionaire | Film Director Jaja Michael starring Bimbo Akintola, Rita Dominic, Kanayo O. Kanayo, Ini Edo | |
2005 | Unknown Angel | Stella | Film Director Ernest Obi starring Ernest Obi, Emeka Eniocha, Ebubu Nwagbo, Tony Umez, Mike Ezuruonye |
2005 | Height Of Indecision | Film Director Ernest Obi starring Amaechi Munagor, Chinyere Wilfred | |
2005 | Baby Guards | Nonye | Film Director Ifeanyi Onyeabo starring Ashley Nwosu, Osita Iheme, Chinedu Ikedieze |
2005 | My Experience | Film Director Oyin starring Emeka Enyioha, Ini Edo, Susuan Patrick, Thelma Okodua | |
2006 | Emotional Blackmail | Film Director Ernest Obi starring Zack Orji, Tony Umez, Mike Ezuruonye, Ini Edo | |
2006 | One Chance | Film Director Emeka Nwabueze starring Oge Okoye, Emeka Nwafor, Francis Duru, Moses Armstrong | |
2006 | Painful World | Vivian | Film Director Willie Ajenge starring Chioma Chukwuka, Desmond Elliot, Mercy Johnson, Moses Effret |
2006 | Honey Desire | Vivian | Film Director Stanley William starring Florence Onuma, Ngozi Orji, Mike Ezuruonye, Monalisa Chinda |
2006 | Edge of Paradise | Chibuzor (2 Episodes) | TV soap. Film Director Greg Odutayo starring Norbert Young, Caroline King, Akeem Rahaman |
2006 | Dangerous Friends | Film Director Ernest Obi starring Steph-Nora Okere, Mike Ezuruonye, Yemi Blaq, Onyeka Onwenu | |
2006 | Nebuchadnezzar | Cynthia | Film Director Stanley William starring Emeka Eniocha, Moses Armstrong, John Okafor |
2006 | Dream come True | Lagbaja's Choice | Musical Video for Musician Lagbaja from the Album "Africano" |
2007 | Saving Sarah | Sarah | Film Director Lancelot Imasuen starring Jim Iyke, Desmond Elliot |
2007 | Devil's Workshop | Nkechi | Film Director Willie Ajenge starring St Obi, Stephanie Okereke |
2007 | Classical Fraud | Cynthia | Film Director Ifeanyi starring Dakore Egbuson, Alex Usifo, Florence Onuma, Clem Ohameze |
2007 | Mortal Man | Marian | Film Director Gloriana James Robert starring Mike Ezuruonye, Emeka Eniocha |
2007 | Sounds of Poverty | Ene | Film Director Suuny Okwori starring Monalisa Chinda, Susan Peters |
2007 | Super story ( Everything It Takes ) | Joke | TV series. Film Director Andy Amenechi starring John Njamah, Kalu Ikeagwu, Paul Adams, Gloria Young, Gbenga Richards |
2007 | Twist of Fate | Vivian | Film Director Willie Ajenge starring Desmond Elliot, Mercy Johson, Moses Effret |
2007 | A Night in the Philippines | Amarachi | Film Director Zeb Ejiro starring Ibinabo Fiberesima, Desmond Elliot Mary Eboka |
2007 | Buy Me a Rose | Rich | Film Director Ernest Obi starring Dakore Egbuson, Ramsey Nouah, Bukky Ajayi, Arinze Okonkwo |
2007 | Titanic Tussle | Mrs Owolabi | Film Director Andy Amenechi starring Kenneth Okonkwo, Mike Ezuruonye Nkiru Sylvanus |
2008 | Rose of Africa | Rich | Film Director Ernest Obi starring Mike Ezuruonye, Dakore Egbuson, Steph Nora Okere, Moses Armstrong, Ramsey Nouah |
2008 | Italian Deal | Lina | Film Director Ernest Obi starring Yvonne Jegede, Mike Ezuruonye, Kalu Ikeagwu, Femi Branch |
2008 | Ice Cold | Film Director Nnamdi Odunze starring Mike Okon, Alex Usifo, Femi Brainard, Vitalis Ndubisi | |
2008 | Divine Partner | Doctor | Film Director Yinka starring Oge Okoye, Tony Umez bendict Johnson |
2008 | Final Tussle | Mrs Owolabi | Film Director Andy Amenechi starring Desmond Elliot, Eurcharia Anunobi, Kenneth Oknokwo, Mike Ezuruonye |
2009 | Empty Coffin | Lilian | Film Director Emeka Hills starring Zack Orji, Emeka Ike |
2009 | Be Yourself | Film Director Emeka Nwabueze starring Amechi Munagor, Moses Effret | |
2009 | My Mum And I | Lilian Wright | TV series. Film Director Greg Odutayo starring Gbenga Windapo, Taiwo Atigogo. *5 Golden Nymph Nominations at the 2010 Monte Carlo Television Festival. *10 Nominations at The 2010 Terracotta TV and Film Awads |
2010 | Hot Island | Lucy | Film Director Emeka Jonathan starring Emeka Ike, Monalisa chinda |
2010 | Wise In-Law | Stella | Film Director Ikechukwu Onyeka. starring Majid Michel, Charles Inojie, Ngozi Ezeonu, Hafiz Ayetoro |
2010 | Private Storm | Lisa | Film Director Lancelot Odua Imasuen starring Ramsey Nouah, Omotola Jalade Ekeinde, John Duello |
2013 | ‘’Vagary’’ | Xter | Film Director Ejiro Starring: Okey Uzoeshi |
2013 | ‘’This House Is Not For Sale’’ | Esther | Film for TV Director Pat Imobio Starring: Saheed Balogun. |
2014 | ‘’Hear Word’’ | Sister Esther | Stage Director Ifeoma Fafunwa Starring: Dakore Akande, Joke Silva, Ireti Doyle, Bimbo Akintola, Elvina Ibru, Omonor Shomolu |
2014 | ‘’Kin’’ | - | Film Director Pat Imobio Starring Saheed Balogun, Tina Mba |
2015 | ‘’Okoro: The Prince’’ | Queen Idia | Film Director Charles Uwagbai Starring: Alex Usifo, Sam Loco Efe, Edosa Imasuen, Henry Legemah. |
2015 | ‘’Hear Word’’ | Sister Esther, Women Rally, VVF | Stage Director Ifeoma Fafunwa Starring Kate Henshaw, Kemi Akindoju, Joke Silva, Bimbo Akintola, Elvina Ibru. * The play also went on tour in November for Ake Festival in Ogun state and in Lagos on Christmas day. |
2015 | ‘’Merciful’’ | Mercy | Film Director Zeb Ejiro Starring Emmanuel Mensah |
2016 | ‘’Duplicity’’ | Zeinom Cameron-Cole Meinom Cameron-Cole | TV Series Director George Kura Starring: Sadiq Daba, Ireti Doyle, Femi Branch, Anthony Monjaro, Uru Eke, Uti Nwanchukwu, Funnybone Chibunna, Buchi Franklin, Aisha Shaba |
2016 | ‘’Hear Word’’ | Sister Esther, VVF, Women Rally Leader | Stage Director Ifeoma Fafunwa Starring: Joke Silva, Bimbo Akintola, Elvina Ibru, *Local Show; Abuja. *International Premier and tour; Harvard, Connecticut and Amsterdam.[25][26][27][28][29][30] |
2016 | ‘’Wives on Strike’’ | Mama Amina | Film Director Omoni Oboli Starring: Omoni Oboli, Uche Jombo, Chioma Chukwuka, Julius Agwu, Kenneth Okonkwo |
2016 | ‘’This Thing Called Marriage’’ | Ifeyinwa | TV Series Director Blessing Effiom Egbe Starring: Femi Jacobs, Tana Adelana, Jennifer John.[31][32][33][34] |
2016 | ‘’Okafor’s Law’’ | Ify | Film Director Omoni Oboli Starring: Omoni Oboli, Richard Mofe Damijo, Blossom Chukwujekwu, Toyin Aimakhu, Halima Abubakar, Mary Lazarus, Yvonne Jegede, Gabriel Afolayan, Ken Erics, Betty Irabo Tina Mba *City to city official selection at the Toronto International Film Festival [35][36][37][38] |
2017 | The Women | Omoh | Film Director Blessing Effiom Egbe starring Kate Henshaw, Omoni Oboli, Katherine Obiang, Tony Monjaro |
Christmas is Coming | Henri | Film Director Ufuoma McDermott starring Deyemi Okanlawon, Chioma Chukwuka | |
Wives on Strike: The Revolution | Mama Amina | Film Director Omoni Oboli starring Omoni Oboli, Uche Jombo, Chioma Chukwuka, Julius Agwu, Kenneth Okonkwo | |
2018 | Esohe | Eno | Film Director Charles Uwagbai Starring: Jimmy Jean-Louis, Kyle Colton, Desmond Elliot |
2018 | What Just Happened | Professor Oghogho | Film Director Charles Uwagbai Starring: Toyin Abraham, Mike Ezuruonye, Segun Arinze |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "UFUOMA EJENOBOR WEDS IN STYLE: EXCLUSIVE PHOTOS". 26 April 2010. Retrieved 1 May 2011.
- ↑ "Ufuoma McDermott Nee Ejenobor". Retrieved 24 August 2016.
- ↑ "Ufuoma born Ejenobor Married McDermott". Retrieved 24 August 2016.
- ↑ "Film making certificate". Retrieved 24 August 2016.
- ↑ "Ufuoma Ejenobor pregnant again, expecting second child". Archived from the original on 13 August 2015. https://web.archive.org/web/20150813023545/http://www.nollywoodsocial.net/ufuoma-ejenobor-pregnant-again-2nd-baby-on-the-way/. Retrieved 10 August 2015.
- ↑ "Why change of name". Retrieved 29 October 2016.
- ↑ "University of Lagos Alumni". Retrieved 19 July 2010.
- ↑ "Ufuoma McDermott 9 things you should know about actress". Retrieved 23 February 2018.
- ↑ "The Beautiful Life Of Nollywood Actress, Ufuoma McDermott". Archived from the original on 24 February 2018. https://web.archive.org/web/20180224002046/http://www.crestnewsng.com/2017/04/24/beautiful-life-nollywood-actress-ufuoma-mcdermott/. Retrieved 23 February 2018.
- ↑ "Mum and I". Archived from the original on 11 November 2010. Retrieved 19 July 2010. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Royal Roots Has Raised the Bar". Archived from the original on 14 July 2011. Retrieved 19 July 2010. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Royal Roots begins Mum and I on AIT". Archived from the original on 8 June 2009. Retrieved 19 July 2010. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Golden Nymph 2010 Nominees". Archived from the original on 17 July 2011. Retrieved 18 July 2010. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Terracotta 2010 Nominees". Archived from the original on 16 July 2011. Retrieved 18 July 2010. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "TFA 2011 Nominees". Archived from the original on 29 October 2016. Retrieved 29 October 2016.
- ↑ "TFAA 2011 Nominees". Retrieved 29 October 2016.
- ↑ "AMVCA 2014 nominees". Retrieved 29 October 2016.
- ↑ "AMVCA 2014 announced". Retrieved 29 October 2016.
- ↑ "DEA 2015 Nominees". Archived from the original on 29 October 2016. Retrieved 29 October 2016.
- ↑ "DEA 2015 Winners". Archived from the original on 29 October 2016. Retrieved 29 October 2016.
- ↑ "ELOY 2016 announced". Retrieved 29 October 2016.
- ↑ "ELOY 2016 nominees". Archived from the original on 29 October 2016. Retrieved 29 October 2016.
- ↑ "ELOY 2016 nominee List". Retrieved 29 October 2016.
- ↑ "ELOY 2016 vote". Retrieved 29 October 2016.
- ↑ "Hear Word in Frascati". Archived from the original on 27 October 2016. Retrieved 26 October 2016.
- ↑ "Hear Word in Havard". Archived from the original on 27 October 2016. Retrieved 26 October 2016.
- ↑ "Hear Word Actresses". Retrieved 26 October 2016.
- ↑ "Hear Word on Stage". Retrieved 24 August 2016.
- ↑ "Hear Word concludes tour". Retrieved 26 October 2016.
- ↑ "Hear Word". Archived from the original on 27 October 2016. Retrieved 26 October 2016.
- ↑ "Ufuoma, Femi and others". Retrieved 26 October 2016.
- ↑ "Blessing Effiom's This thing called marriage". Retrieved 26 October 2016.
- ↑ "First episode of This Thing Called Marriage". Retrieved 26 October 2016.
- ↑ "This Thing Called Marriage". Retrieved 26 October 2016.
- ↑ "Watch Omoni and others in Okafor's Law". Retrieved 26 October 2016.
- ↑ "Okafor's Law sold out three halls". Retrieved 26 October 2016.
- ↑ "Okafor's Law selected for SIFF". Retrieved 26 October 2016.
- ↑ "TIFF City to City Selection". Retrieved 26 October 2016.