Taslim Olawale Elias
Ìrísí
Taslim Olawale Elias QC LLD CFR GCON | |
---|---|
Ààrẹ Ilé-ẹjọ́ Ìdájọ́ Akáríayé | |
In office 1982–1985 | |
Igbákejì Ààrẹ Ilé-ẹjọ́ Ìdájọ́ Akáríayé | |
In office 1979–1982 | |
Adájọ́ Ilé-ẹjọ́ Ìdájọ́ Akáríayé | |
In office 1976–1991 | |
Asíwájú | Charles D. Onyeama |
Arọ́pò | Prince Bola Ajibola |
Olùdájọ́ Àgbà ilẹ̀ Nàìjíríà | |
In office 1972–1975 | |
Agbẹ́jọ́ Àgbà àti Aránṣẹ́ọba fún Ìdájọ́ Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Nàìjíríà | |
In office 1966–1972 | |
Agbẹ́jọ́ Àgbà àti Alákóso Ìdájọ́ 1k Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Nàìjíríà | |
In office 1960–1966 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Lagos, Nigeria | 11 Oṣù Kọkànlá 1914
Aláìsí | 14 August 1991 Lagos, Nigeria | (ọmọ ọdún 76)
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Alma mater | University College, London (B.A., LL.B, LL.M, Ph.D) |
Taslim Olawale Elias (November 11, 1914 – August 14, 1991) je oludajo ara Naijiria. O je Aare Ile-Ejo Idajo Akariaye ati Oludajo Agba Ile-Ejo Gigajulo ile Naijiria tele. Bakanna o kopa ninu isodotun ati atunse awon ofin Naijiria.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |