Jump to content

Ìpínlẹ̀ Sokoto

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Sokoto State)
Ipinle Sokoto
State nickname: Seat of the Caliphate
Location
Location of Sokoto State in Nigeria
Statistics
Governor
(List)
Aminu Waziri Tambuwal (PDP)
Date Created 3 February 1976
Capital Sokoto
Area 25,973 km²
Ranked 16th
Population
1991 Census
2005 est.
Ranked 14th
4,392,391
4,244,399
ISO 3166-2 NG-SO

Ipinle Sokoto jé ikan ninu awon ipinle mérìndilógún tí o wà ní orile-ede Naijiria. Ìpínlè Sokoto wà ní àríwá ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríà [1]Oruko gomina ipinle sokoto lowolowo bayii ni arakunrin Tanbuwal

Awọn ijọba íbílẹ̀ tí ó wà nì ìpínlẹ̀ Sokoto jẹ́ mẹ́tàlẹ́lógún. Awon na ni:

  • Binji
  • Bodinga
  • Dange Shuni
  • Gada
  • Goronyo
  • Gudu
  • Gwadabawa
  • Illela
  • Isa
  • Kebbe
  • Kware
  • Rabah
  • Sabon Birni
  • Shagari
  • Silame
  • Sokoto North
  • Sokoto South
  • Tambuwal
  • Tangaza
  • Tureta
  • Wamako
  • Wurno
  • Yabo

Ilé ẹ̀kọ́ gíga

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Usman Danfodio University of Sokoto[2]
  • Sokoto State University[3]
  • Umaru Ali Shinkafi Polytechnic Sokoto[4]
  • Shehu Shagari College of Education[5]
  1. "Sokoto - state, Nigeria". Encyclopedia Britannica. 2012-09-10. Retrieved 2022-03-04. 
  2. "UDUSOK Courses | List of BSc Programmes in Usmanu Danfodiyo University" (in en-US). 2020-10-09. https://www.myschoolgist.com/ng/udusok-courses/. 
  3. ago, Adole Michael Adole 3 years (2018-03-15). "List of Courses Offered at Sokoto State University (SSU)". Nigerian Scholars (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-11-22. 
  4. "List of Courses Offered at Umaru Ali Shinkafi Polytechnic Sokoto". Nigerian Scholars (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-01-15. Retrieved 2021-11-22. 
  5. Blog, Real Mina (2019-03-06). "List of Courses in Shehu Shagari College Of Education, Sokoto (SSCOESOK)". Real Mina Blog (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-11-22. Retrieved 2021-11-22.