Jump to content

Sika Osei

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Sassy Sika Osei
Sika Osei in April 2019 on Fashion Insider
Ọjọ́ìbí1985 (ọmọ ọdún 38–39)
Ghana
Orílẹ̀-èdèGhanaian
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Ghana
Iṣẹ́Actress, Producer, Model
Gbajúmọ̀ fúnDStv's Studio 53 extra, NadiTV's Fashion Insider
Notable workGuilty, 3N
Olólùfẹ́Sele Douglas
AwardsGolden Movie Awards

Sassy Sika Osei (tí wọ́n bí ní ọdún 1985) jé òsèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Ghana, béè sì ní ó jẹ́ olóòtú ètò orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán tó ti ṣiṣẹ́ aṣojú fún àwọn ilé-iṣẹ́ bí i L’Oreal Paris àti Woodin.[1][2]

Ìgbésí ayé ara ẹni

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní 22 October 2021, Osei ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú Sele Douglas ní ìlú Accra, ní Ghana.[3][4]

Àwọn fíìmù rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Grey Dawn (2015) as Flora Davies
  • The Counselor[5] (2015)
  • 3 Nights Ago (2016) as Ewurama
  • In Line (2017) as Bella
  • Hustle[6]
  • Public Property (2017)
  • Bad Luck Joe (2018) as Zuri Turkson
  • Sidechic Gang (2018) as Fella
  • Joseph (2020) as Abena
  • Little Problems (2021) as Pokua
  • Single Not Searching (2022) as Kisi
  • Nine (2023) as Lauren

As producer

  • Guilty[7] (2015)
  • 3NA (2016)

Àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Photos: All you need to know about actress Sika Osei". GhanaWeb. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-09-28. 
  2. "Sika Osei Biography – Age". MyBioHub (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-04-08. Retrieved 2019-09-28. 
  3. "Actress and presenter Sika Osei ties the knot". My Joy Online. 22 October 2021. Retrieved 21 April 2022. 
  4. Debrah, Ameyaw (24 October 2021). "Highlights From Sika Osei And Sele Douglas' White Wedding - Ameyaw Debrah". Ameyaw Debrah. Retrieved 21 April 2022. 
  5. "Sika Osei". Ghana Film Industry (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-09-28. Retrieved 2019-09-28. 
  6. "Sika Osei". Africa Magic Official Website – Sika Osei (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-09-28. 
  7. "Sika Osei: Bold and brilliant". Guardian Nigeria. Retrieved 2019-09-28. 
  8. Abdullai, Isshak. "Full list of winners at 2018 Golden Movie Awards Africa". YFM Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-09-28. 
  9. "Full list of winners at 2018 Golden Movie Awards Africa". GhanaWeb (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-09-28. 
  10. "Dumelo, McBrown and the full list of winners at 2018 Golden Movie Awards". pulse ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-06-04. Retrieved 2019-09-28. 
  11. "2019 Golden Movie Awards: Full list of nominees released". Myjoyonline. Retrieved 2019-09-28. 
  12. "AMAA 2018 Full List Of Winners". ama-awards. Archived from the original on 2019-10-24. Retrieved 2019-09-28. 
  13. "Sika Osei nominated for Lagos 30 Under 40 Award". The Ghana Guardian News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-09-28. 

Àdàkọ:Authority control