Sani Musa Danja
Sani Musa Danja | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 20 Oṣù Kẹrin 1973 Fagge, Kano, Nigeria[1] |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iṣẹ́ | Òṣèré orí-ìtàgé, Olùgbéré-jáde, Adarí eré àti Singer, Alájótà |
Olólùfẹ́ | Mansura Isa |
Àwọn ọmọ | 4 |
Sani Musa Abdullahi, tí wọ́n tún mọ̀ sí Sani Danja tàbí Danja tí wọ́n bí ní ogúnjọ́ oṣù Kẹrin ọdún 1973 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, olùgbéré-jáde, alájótà àti olórin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà .[2] Ó kópa nínú àwùjọ Kannywood àti Nollywood.[3] Ní oṣù Kẹ́rin ọdún 2018, tí ó jẹ́ Etsu Nupe , Yahaya Abubaka, wé láwàní fun gẹ́gẹ́ bí Zakin Arewa. [4][5]
Iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ eré ìtàgé Hausa ní ọdún 1999 nínú eré Daliba. Danja ti gbé àwọn eré ó sì ti darí àwọn eré bíi: Manakisa, Kwarya tabi Kwarya, Jaheed, Nagari, Wasiyya, Harsashi, Gidauniya, Daham, Jarida, Matashiya, àti àwọn mìíràn. Danja di ìlú-mòọ́ká ní ọdún 2012 nínú eré Daughter of the River. [6][7]
Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Sani ti kópa nínú eré , ó sì ti gbé eré jáde ó sì ti darí eré Kannywood àti Nollywood. Lárà rẹ̀ ni :[8]
Àkọ́lé eré | Ọdún |
---|---|
Yar agadez | 2011 |
A Cuci Maza | 2013 |
Albashi (The salary) | 2002 |
Bani Adam | 2012 |
Budurwa | 2010 |
Da Kai zan Gana | 2013 |
Daga Allah ne'’ (Is from the God) | 2015 |
Daham | 2005 |
Dan Magori | 2014 |
Duniyar nan | 2014 |
Fitattu | 2013 |
Gani Gaka | 2012 |
Gwanaye | 2003 |
Hanyar Kano | 2014 |
Kukan Zaki (The lion's cry) | 2010 |
The other side | 2016 |
Buri uku a duniya (Three wishes in the world) | 2016 |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Sani Danja [HausaFilms.TV – Kannywood, Fina-finai, Hausa Movies, TV and Celebrities]". hausafilms.tv. Retrieved 21 January 2019.
- ↑ Blueprint (2017-10-14). "It pains how people download our films – Danja". Blueprint Newspapers Limited (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-09-24.
- ↑ "Nollywood – Kannywood Scene". Retrieved 5 February 2019.
- ↑ "Kannywood actor, Sani Danja Turbaned as Zaki Af Arewa". Modern Ghana. 26 April 2018. Retrieved 21 January 2019.
- ↑ "Kannywood: Sani Danja turbaned by Etsu Nupe". Premium Times Nigeria. 10 August 2017. Retrieved 21 January 2019.
- ↑ "Kannywood Star Actor Becomes Richest Northern Entertainer". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-09-26. Retrieved 2020-09-24.
- ↑ "Kannywood actor, Sani Danja, makes Nollywood debut". Premium Times Nigeria. 1 September 2012. Retrieved 22 January 2019.
- ↑ "Sani Danja [HausaFilms.TV – Kannywood, Fina-finai, Hausa Movies, TV and Celebrities]". hausafilms.tv. Retrieved 23 January 2019.