Quett Masire
Ìrísí
Quett Ketumile Joni Masire | |
---|---|
2nd Aare ile Botswana | |
In office July 13, 1980 – March 31, 1998 | |
Asíwájú | Seretse Khama |
Arọ́pò | Festus Mogae |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 23 Oṣù Keje 1925 Kanye, Botswana (nigbana bi Ileabo ti UK) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Egbe Toseluarailu Botswana (BDP) |
Quett Ketumile Joni Masire, GCMG (ojoibi July 23, 1925 ni Kanye, Botswana) je oloselu ati Aare ikeji orile-ede Botswana lati 1980 de 1998, o je omo egbe oloselu Egbe Toseluarailu Botswana. Nigba to kosesile ni 1998, Festus Mogae to je Igbakeji Aare ropo re lati di Aare ile Botswana keta.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |