Muyiwa Ademola
Muyiwa Ademola | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ́n, Oṣù Ṣéẹ́rẹ́ ọdún 1971 |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Naijiria |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Yunifásítì Ìjọba Àpapọ̀ tí Ìlú Ibadan |
Notable work | Alápadúpẹ́ |
Muyiwa Ademola (a bi ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ́n, Oṣù Ṣéẹ́rẹ́ ọdún 1971) jẹ́ ògbóǹtarìgì òṣèré àti olùdarí sinimá àgbéléwò ọmọ Yorùbá lorílẹ̀èdè Nàìjíríà. Ní ọdún 2005, fíìmù rẹ̀ ORÍ gbá àmì-ẹ̀yẹ eré abínibí tó dára jù lọ ní 1st Africa Movie Academy Awards. Ní ọdún 2008, wọ́n yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ òṣèrékùnrin abínibí tó peregedé julọ̀.
.[1][1]
Ibẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ìgbé-ayé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bí Muyiwa Ademola ni ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ́n oṣù Ṣẹ́ẹ́rẹ́, 1971 ní ìlú Abẹ́òkúta , tíì ṣe olú ìlú Ìpínlẹ̀ Ògùn Ogun ní Nàìjíríà.[1]. O si lọ si St. David's High School ni Mọ̀lété ní Ìbàdàn ibi tí ó ti gba West Africa Secondary School Certificate.[2]. Ó tẹ̀síwájú sí Yunifásítì Ìjọba Àpapọ̀ tí Ìlú Ibadan ibi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ìmọ̀ Ẹ̀kọ́ Àgbà (B.ED) in Adult Education.
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Muyiwa Adémọ́lá ti ipasẹ̀ Charles Olúmọ tí a mọ̀ sí Àgbákò tí ó fi ìlú rẹ̀ Abẹ́òkúta .[5]. ṣe ibùgbé darapọ̀ mọ́ agbo àwọn òṣèré. Ó ṣe alábàápàdé olùdarí eré kan tí ó ń jẹ́ S. I Ọlá tí ó kọ ní eré ṣíṣe àti fíìmù gbígbé jáde. Ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe rẹ̀ ní ọdún 1991.[6] Ní ọdún 1995, ó gbé eré rẹ̀ àkọ́kọ́ jáde ti ó pè ní Àṣìṣe. Iléeṣẹ́ Dibel ló ṣe àgbátẹrù eré náà. Láti ọdún 1995, ó ti gbé, darí àti hàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré Yorùbá. Ní Ṣéẹ́rẹ́ ọdún 2013, ìròyìn sọ pé ó ní ìjàmbá ọkọ èyí tí ó kú díẹ̀ kí ó mú ẹ̀mí rẹ̀ lọ
Àwon fiimu tí ó ti kópa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Àṣìṣe (1995)
- Ilẹ̀
- Orí
- Ami Ayo
- Fimi dára Ire[9]
- Ìránṣẹ́ Ajé
- "J J
- Alápadúpẹ́
E tun wo
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- 4th Africa Movie Academy Awards
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Agu, Zain (2018-12-07). "Muyiwa Ademola ★ top facts from his biography". Legit.ng - Nigeria news. Archived from the original on 2019-09-22. Retrieved 2019-09-22.
- ↑ Tolu. "Actor, Muyiwa Ademola Shares Photos Of His Lovely Wife And Kids". INFORMATION NIGERIA. Retrieved 3 January 2015.
- ↑ "Actor Muyiwa Ademola Confirms Accidents Story to Nigeriafilms.com - nigeriafilms.com". Retrieved 3 January 2015.
- ↑ "Muyiwa Ademola is a close friend, not my lover — Sexy Winger - Vanguard News". Vanguard News. Retrieved 3 January 2015.
- ↑ "Popular Actor, Muyiwa Ademola Loses Dad". thenigerianvoice.com. Retrieved 3 January 2015.
- ↑ http://tribune.com.ng/glamour/item/11749-it-costs-me-good-money-to-look-good-mosun-filani/11749-it-costs-me-good-money-to-look-good-mosun-filani
- ↑ http://tribune.com.ng/glamour/item/11749-it-costs-me-good-money-to-look-good-mosun-filani/11749-it-costs-me-good-money-to-look-good-mosun-filani
- ↑ "More sad news in Nollywood: Actor Muyiwa Ademola involved in fatal accident". DailyPost Nigeria. Retrieved 3 January 2015.
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2015-01-03. Retrieved 2017-03-15.