Mercedes Ruehl
Mercedes Ruehl ni a bini ọjọ kèji dinlọgbọn óṣu february ni ọdun 1948 jẹ Óṣèrè lobinrin to gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo[1].
Igbèsi Àyè Àràbinrin naa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ruehl ni a bisi Jackson Heights, Queens, New York City fun Mercedes J. Ruehl (Ólukọ) ati Vincent Ruehl (Agenti ti FBI)[2]. Babà óṣèrè lobinrin naa wa lati iràn German ati Irish, Iya rẹ wa lati iran Cuban ati Irish. Ruehl ni ó dàgbà si ilanà Catholic[3].
Óṣèrè lobinrin naa bẹrẹ irin àjó iṣẹ rẹ ni theatre pẹlu Ilè iṣẹ Denver Center Theatre. Ni ọdun 1999, Ruehl fẹ David Geiser ti ó jẹ painter. Óṣèrè gba ọmọ ọkunrin kan tọ ti órukọ rẹ njẹ Jake ti a bini ọdun 1995. David Geiser ku lójiji ninu órun rẹ ni ilè rẹ ni ọjọ kẹrin dinlógun óṣu October ni ọdun 2020 lori aisan ọkan[4][5].
Ẹkọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ruehl lọsi collegi ti New Rochelle ti ó si kàwè ja pẹlú BA lori èdè gẹẹsi ni ọdun 1969[6].
Ami Ẹyẹ ati Idanilọla
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdun | Àkọlè | Accolade | Èsi |
---|---|---|---|
1989 | Married to the Mob | National Society of Film Critics Award, Best Supporting Actress | Óṣèrè lóbinrin naa yègè |
1991 | The Fisher King | Boston Society of Film Critics Award, Best Supporting Actress | Óṣèrè lóbinrin naa yègè |
Lost in Yonkers | Drama Desk Award, Outstanding Actress in a Play | Óṣèrè lóbinrin naa yègè | |
The Fisher King | Los Angeles Film Critics Association Award, Best Supporting Actress | Óṣèrè lóbinrin naa yègè | |
Lost in Yonkers | Tony Award, Best Performance by a Leading Actress in a Play | Óṣèrè lóbinrin naa yègè | |
The Fisher King | Venice Film Festival Award, Best Lead Actress | Óṣèrè lóbinrin naa yègè | |
1992 | Academy Award, Best Supporting Actress | Óṣèrè lóbinrin naa yègè | |
American Comedy Award, Funniest Supporting Actress in a Motion Picture | Óṣèrè lóbinrin naa yègè | ||
Chicago Film Critics Association Award, Best Supporting Actor | Óṣèrè lóbinrin naa yègè | ||
Dallas-Fort Worth Film Critics Association Award, Best Supporting Actress | Óṣèrè lóbinrin naa yègè | ||
Golden Globe Award, Best Supporting Actress in a Motion Picture | Óṣèrè lóbinrin naa yègè | ||
Saturn Award, Best Supporting Actress | Óṣèrè lóbinrin naa yègè | ||
1993 | Boston Film Festival Award, Film Excellence award | Óṣèrè lóbinrin naa yègè | |
1995 | Indictment: The McMartin Trial | CableACE Award, Best Actress in a Movie or Miniseries | Wọn yan |
The Rose Tattoo | Drama Desk Award, Outstanding Actress in a Play | Wọn yan | |
The Shadow Box | Tony Award, Best Performance by a Featured Actress in a Play | Wọn yan | |
2002 | The Goat, or Who Is Sylvia? | Tony Award, Best Performance by a Leading Actress in a Play | Wọn yan |
2006 | Mom at Sixteen | Prism Award, Performance in a Television Movie or Miniseries | Wọn yan |
2007 | A Girl Like Me: The Gwen Araujo Story | Imagen Foundation Award, Best Actress - Television | Wọn yan |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://www.broadwayworld.com/people/Mercedes-Ruehl/
- ↑ http://www.filmreference.com/film/30/Mercedes-Ruehl.html
- ↑ https://web.archive.org/web/20131029185422/http://www.playbill.com/features/article/125033-STAGE-TO-SCREENS-Mercedes-Ruehl-the-Macy-Mamet-Connection-and-Remembering-Brad-Sullivan
- ↑ https://web.archive.org/web/20110726144552/http://movies.yahoo.com/movie/contributor/1800019603/bio
- ↑ https://www.easthamptonstar.com/obituaries/2020115/david-geiser-artist-was-73
- ↑ https://web.archive.org/web/20130507041128/http://www2.cnr.edu/CNR/cnr-wealth.html