Lafia
Ìrísí
Lafia Lafiyan | |
---|---|
LGA and town | |
Nickname(s): Lafia Garin Madidi | |
Coordinates: 8°29′30″N 8°31′0″E / 8.49167°N 8.51667°E | |
Country | Nigeria |
State | Nasarawa State |
Government | |
• Emir | Hon. Justice Sidi Bage Muhammad I JSC Rtd. |
• LGA Chairman | Alh. Aminu Mu'azu Maifata |
Population (2006) | |
• Total | 330,712 |
[1] | |
Time zone | UTC1 (WAT) |
Climate | Aw |
Lafia jẹ́ ìlú kan ní àárín gbùngbùn Gúúsù ilẹ̀ Nàìjíríà. Òun ni olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Nasarawa ó sì ní àwọn olùgbé tí ó tó 330,712 ènìyàn gẹ́gẹ́ bí ètò ìkànìyàn ọdún 2006 ní Nàìjíríà sọ.[1] Òun ni ìlú tí ó tóbi jù ní ìpínlẹ̀ Nasarawa.
Ìtàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn míràn mo ìlú Lafia sí Lafian bare-Bari. Muhammadu Dunama ni ó dá ìlú náà kalẹ̀ ní ọdún 17k.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn Ìtókasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 [1] Archived June 26, 2011, at the Wayback Machine.