Jump to content

Kang Young - Hoon

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

kang Young-Hoon (o gbè ayé ni oṣù kàrún ọjọ ọgbọn, ọdún 1922 sí oṣù kàrún ọjọ kẹwàá,2016) o jẹ Àgbà olóṣèlú ni orilẹ ède South Korea Kan. O jẹ Alákòóso àgbà tí orilẹ ède South Korea láti ọjọ kàrún oṣù Kejìlá ọdún 1988 títí di ọjọ kẹtadinlọgbọn oṣù Kejìlá ọdún 1990,o tún jẹ adele alákòóso mínísítà títí di ọjọ kẹ̀rindinlogun oṣù Kejìlá.


Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]