Jump to content

Gloria Grahame

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Gloria Grahame
Gloria Grahame
Ọjọ́ìbíGloria Grahame Hallward
(1923-11-28)Oṣù Kọkànlá 28, 1923
Los Angeles, California, U.S.
AláìsíOctober 5, 1981(1981-10-05) (ọmọ ọdún 57)
New York City, New York, U.S.
Resting placeOakwood Memorial Park Cemetery
Iṣẹ́Actress, singer
Ìgbà iṣẹ́1944–1981
Political partyDemocratic
Olólùfẹ́
Stanley Clements
(m. 1945; div. 1948)

Nicholas Ray
(m. 1948; div. 1952)

Cy Howard
(m. 1954; div. 1957)

Anthony Ray
(m. 1960; div. 1974)
Àwọn ọmọ4


Gloria Grahame je óṣèrè lóbinrin ati akọrin ilẹ america to gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo[1].

Ìgbèsi Àyè Àrabinrin naa

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Grahame ni à bisi Los Angeles. Óṣèrè lóbinrin naa ni à tọ ni ilana Methodist. Baba Gloria Reginald Michael Bloxam jẹ architect ti ilẹ èdè gẹẹsi ati ólùkọwè ṣùgbọn iya rẹ Jean McDougall jẹ óṣèrè lòbinrin ilẹ british[2].

Grahame jẹ Democrat to ti Adlai Stevenson lẹyin lóri campaign rẹ̀ lori idibó arẹ ni ọdun 1952.

Grahame fẹ ọkọ lẹẹmẹrin to si bi ọmọ mẹrim. Óṣèrè lobinrin naa ṣè Igbeyawó akọkọ pẹlu óṣèrè lọkunrin Stanley Clements ni óṣu August, ọdun 1945. Tọkọ Taya pinya ni ọdun 1948. Glori fẹ Director Nicholas Ray ti wọn si bi ọmọ ọkunrin Timothy ni óṣu November, ọdun 1948. Tọkọ Taya pinya ni ọdun 1952. Glori ṣè Igbeyawó kẹta pẹlu ólukọwè ati óludari television Cy Howard ni óṣu August, ọdun 1954 ti wọn si bi ọmọ óbinrin Marianna Paulette ni ọdun 1956. Tọkọ Taya pinya ni óṣu November, ọdun 1957. Gloria ṣè Igbèyawó kẹrin pẹlu óṣèrè lọkunrin Anthony Ray (Ọmọ ọkọ rẹ ẹlẹkèji) ni óṣu May, ọdun 1960 ti wọn si bi ọmọ ọkunrin meji; Anthony ni ọdun 1963 ati James ni ọdun 1965[3][4].

Ni óṣu March, ọdun 1974 Gloria ni arun jẹjẹrẹ ti ọmu. Ni ọdun 1981, ósèrè lóbinrin naa ṣè aisan tosi yẹ ki wọn ṣiṣè abẹ fun ṣugbọn ó kọ jalẹ. Ni óṣu October, ọdun 1981 Gloria kus si Ilè iwósan St Vincent ni Manhattan, New York City. Óṣèrè lóbinrin naa ni wọn sin si Oakwood Memorial Park Cemetery ni Chatsworth, Los Angeles[5][6].

Grahame lọ si ilè iwe Hollywood High School lẹyin naa ni àràbinrin naa kurò nibẹ lati tẹsiwaju lóri irin ajo èrè ṣiṣè[7].

Ipà Óṣèrè lóbinrin ninu èrè àgbèlèwó

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ọdun Akọlè Ipa Óṣèrè lóbinrin Notes
1944 Blonde Fever Sally Murfin Alternative title: Autumn Fever
1945 Without Love Flower girl
1946 It's a Wonderful Life Violet Bick
1947 It Happened in Brooklyn Nurse
1947 Crossfire Ginny Tremaine Nominated – Academy Award for Best Supporting Actress
1947 Song of the Thin Man Fran Ledue Page
1947 Merton of the Movies Beulah Baxter
1949 A Woman's Secret Susan Caldwell aka Estrellita
1949 Roughshod Mary Wells
1950 In a Lonely Place Laurel Gray
1952 The Greatest Show on Earth Angel
1952 Macao Margie
1952 Sudden Fear Irene Neves
1952 The Bad and the Beautiful Rosemary Bartlow Academy Award for Best Supporting Actress
Nominated – Golden Globe Award for Best Supporting Actress – Motion Picture
1953 The Glass Wall Maggie Summers
1953 Man on a Tightrope Zama Cernik
1953 The Big Heat Debby Marsh
1953 Prisoners of the Casbah Princess Nadja aka Yasmin
1954 The Good Die Young Denise Blaine
1954 Human Desire Vicki Buckley
1954 Naked Alibi Marianna
1955 The Cobweb Karen McIver
1955 Not as a Stranger Harriet Lang
1955 Oklahoma! Ado Annie Carnes
1956 The Man Who Never Was Lucy Sherwood
1957 Ride Out for Revenge Amy Porter
1959 Odds Against Tomorrow Helen
1966 Ride Beyond Vengeance Bonnie Shelley
1971 Blood and Lace Mrs. Deere
1971 The Todd Killings Mrs. Roy
1971 Chandler Selma Alternative title: Open Shadow
1972 The Loners Annabelle
1973 The Magician Natalie Alternative title: Tarot
1974 Mama's Dirty Girls Mama Love
1976 Mansion of the Doomed Katherine Alternative title: The Terror of Dr. Chaney
1979 A Nightingale Sang in Berkeley Square Ma Fox
1979 Head Over Heels Clara Alternative title: Chilly Scenes of Winter
1980 Melvin and Howard Mrs. Sisk
1981 The Nesting Florinda Costello Alternative titles: Phobia and Massacre Mansion

Ami Ẹyẹ ati Idanilọla

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Gloria gba Àmi Ẹyẹ ti Oscar ati Golden Globe.Fun ipa Óṣèrè lóbinrin naa ni motion picture industry, Gloria gba irawọ star lori Hollywood Walk of Fame ni 6522 Hollywood Boulevard[8][9].