George Read
Ìrísí
George Read jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí ó tọwọ́ bọ̀wé fún ìfilọ́lẹ̀ ìgbòmìnira orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.[1] Ní ọdún 1753, wọ́n gba George Read wọlé gẹ́gẹ́ bí i ọmọ ẹgbẹ́ amòfin sílé ẹjọ́.[2][1]
Ó jẹ́ olówó àti ọlọ́rọ̀, tí ó sì jẹ́ gbajúgbajà amòfin. Ọmọ rẹ̀ kan ń jẹ́ John Read.[3]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 Numbers, the (2020-01-19). "George Read - One of America's Founding Fathers". The Constitutional Walking Tour of Philadelphia. Retrieved 2023-02-03.
- ↑ "A Biography of George Read 1733-1798 < Biographies < American History From Revolution To Reconstruction and beyond". let.rug.nl. Retrieved 2023-02-03.
- ↑ Pessen, E.. Riches, Class and Power. Transaction Publishers. p. 125. ISBN 978-1-4128-3332-5. https://books.google.com.ng/books?id=URRT5eSDGaUC&pg=PA125. Retrieved 2023-02-03.