Folakunle Oshun
Ìrísí
Folakunle Oshun | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ibadan, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹ̀kọ́ | |
Iṣẹ́ | Visual artist, sculptor and curator |
Gbajúmọ̀ fún | Lagos Biennal, Potsdam Curator Award 2017 |
Website | folakunleoshun.com |
[1].[2][3].[4][5][6][7]Folakunle Oshun ( Tí wọ́n bí ní ọdún 1984 ní Ìpínlẹ̀ Ìbàdàn) jẹ́ Oníṣẹ́ọna amọ_ère , Agbẹ́giléré ní Orílẹ̀_ èdè Nàìjíríà.
Òun ni Olùdásílẹ̀ àti Olùdarí Lagos Biennal, Àjọ tí ó pèsè àyè fún ìfọ̀rọ̀wọ́rọ̀ àti ìdàgbàsókè tí iṣẹ́onà Áfíríkà. Àwọn iṣẹ́ ọnà Oshun ti perí ní ọpọ ìgbà nílẹ̀ yìí àti lókè òkun.
Early life and education
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀].[8][9]Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ àti Ẹ̀kọ́ = Folakunle Oshun jẹ́ ọmọ tí wọ́n bí tí ó sì dàgbà ní ìpínlè Ọ̀yọ́ ní ìlú Ìbàdàn, ní orílè èdè Nàìjíríà. Ó lọ sí ilé Ẹ̀kó gíga University of Lagos, ibi tí ó ti kọ́ ẹ̀kọ́ gboyè nínú B.A Fine Arts(2004_2007) àti M.A ní Art History (2008_2012). Guardian Nigerian News_Nigeria and World News Language.
Ìṣàfihan iṣẹ́_ Ọnà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Selected curatorial:
- Afrique 2020 season in France 2021
- Look at This Pinakothek der Moderne, Munich 2021.[10]
- Museum of Hope, Berliner Dom 2021[11][12][13]
- 'How to Build a Lagoon With Just A Bottle of Wine?' Lagos Biennial, Lagos (Nigeria) 2019.[14]
- Living on the Edge, Lagos Biennial, Lagos 2017.[15]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Pilot project Curators in Residence Potsdam". State Capital Potsdam (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-03-07. Retrieved 2021-08-11.
- ↑ "Lagos Biennial gets curators". Latest Nigeria News, Nigerian Newspapers, Politics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-02-19. Retrieved 2021-08-12.
- ↑ "LAGOS BIENNIAL". The Lagos Biennial (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-08-12. Retrieved 2021-08-11.
- ↑ "Oshun, Folakunle". www.goethe.de (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-08-11.
- ↑ Editors, T. S. A. (2019-11-01). ""How to Build a Lagoon with Just a Bottle of Wine": A Review of Lagos Biennial 2019 | By Kovie Parker". The Sole Adventurer (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-08-11.
- ↑ "Folakunle Oshun | People - ZK/U Berlin". www.zku-berlin.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-08-11.
- ↑ Mitter, Siddhartha (2019-02-08). "Lagos, City of Hustle, Builds an Art 'Ecosystem'" (in en-US). The New York Times. ISSN 0362-4331. https://www.nytimes.com/2019/02/08/arts/design/lagos-nigeria-art-x-art.html.
- ↑ Olaniyan, Oyinda (2019-02-18). "Ask the Curator: Folakunle Oshun". Omenka Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-08-12. Retrieved 2021-08-11.
- ↑ "FOLAKUNLE OSHUN". chinafrika.org. Retrieved 11 August 2021.
- ↑ "ZEIT ONLINE | Lesen Sie zeit.de mit Werbung oder im PUR-Abo. Sie haben die Wahl.". www.zeit.de. Archived from the original on 2021-08-12. Retrieved 2021-08-12.
- ↑ altafrica10 (2021-07-23). "Berlin: Folakunle Oshun presents Museum of Hope". Bespoke ARTS Guide (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-08-11.
- ↑ "Der nigerianische Künstler Folakunle Oshun". www.rbb-online.de (in Èdè Jámánì). Retrieved 2021-08-11.
- ↑ "Museum of Hope | Berliner Dom". www.berlinerdom.de. Archived from the original on 2021-08-12. Retrieved 2021-08-11.
- ↑ "Lagos Biennial 2019: Stories from Africa's most Populous City". ocula.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-08-12. Retrieved 2021-08-12.
- ↑ "Life in Lagos imitates art as squatters evicted for biennial exhibition". the Guardian (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-10-26. Retrieved 2021-08-12.
- Dak’art 2016[1]Àdàkọ:Failed verification
- ↑ Welle (www.dw.com), Deutsche. "Dak'Art 2016 presents rich variety of contemporary African art | DW | 06.05.2016". DW.COM (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-08-12.