Eva Marcille
Ìrísí
Eva Marcille Sterling (tí orúkọ bàbá rẹ̀ jẹ́ Pigford; tí a bí ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù kẹwàá, ọdún 1984) jẹ́ òṣèrébìnrin ti ilẹ̀ Amerika, oníṣé-oge, àti gbajúgbajà lórí ẹ̀rọ amóhùn-máwòrán.[1] Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ nígbà tó jáwé olúborí nínú ìdíje ẹlẹ́ẹ̀kẹta ti America's Next Top Model.
Ìbẹ̀rẹ̀pèpẹ̀ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bí arábìnrin Sterling ní ìlú Los Angeles, California, orúkọ àbísọ rẹ̀ sì ni Eva Pigford.
Iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Iṣẹ́ aláwòṣe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Nínú ìdíje ẹlẹ́ẹ̀kẹta ti America's Next Top Model ní ọdún 2004, Marcille jáwé olúborí [2] nínú ìfigagbágba pẹ̀lú Yaya DaCosta.
Ìgbésí ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní oṣù keje, ọdún 2006, Marcille bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe wolé-wọ̀de pẹ̀lú òṣèrékùnrin Lance Gross. Àwọn olólúfẹ́ méjèèjì fẹ́ ara wọn ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kejìlá, ọdún 2008, tí wọ́n sì tú ká ní oṣù kẹta, ọdún 2010.[3]
Àtòjọ àwọn eré tí ó ti ṣe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Fíìmù agbéléwò
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àkórí | Ipa | Ìsọníṣókí |
---|---|---|---|
2005 | The Walk | Sydney Lee | Video |
2006 | Premium | Farrah | |
Crossover | Vanessa | ||
The Wedding Album | Gretchen | TV movie | |
2007 | I Think I Love My Wife | Hope | |
2009 | Super Capers | News Reporter | |
2011 | The Boys and Girls Guide to Getting Down | Jasmine | TV movie |
2012 | If You Really Love Me | ||
Note to Self | Karen Wells | ||
2013 | 24 Hour Love | Leah | |
2014 | The Fright Night Files | Marla Peters | TV movie |
For the Love of Lockwood | |||
2015 | For the Love of Lockwood Too | ||
Sister Code | Sheila | ||
2017 | The Cheaters Club | Olive | |
Miss Me This Christmas | Trish McDonald | ||
2021 | Adventures in Christmasing | Vh1 original movie | |
2022 | Hello | Alicia Gregory | TV movie |
2022 | A Christmas Fumble | Nicole Barnes | BET Plus movie |
2022 | A New Diva’s Christmas Carol | Zero | Vh1 original movie |
Eré rẹ̀ lórí ẹ̀rọ amóhùn-máwòrán
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Title | Role | Notes |
---|---|---|---|
2004 | America's Next Top Model | Herself/Contestant | Main cast: Season 3 |
2005 | Best Week Ever | Herself | Episode: "Michael Jackson trial, the OC and More" |
Wild 'n Out | Herself | 2 episodes | |
Kevin Hill | Sandra Clark | 2 episodes | |
2007 | The Game | Herself | Episode: "Out of Bounds" |
Smallville | Tyler Crenshaw | Episode: "Fierce" | |
Everybody Hates Chris | Ms. Crabtree | Episode: "Everybody Hates Minimum Wage" | |
2007–12 | Tyler Perry's House of Payne | Tracie Evans | Recurring cast: Season 1–2, 5–7 & 10 |
2008–09 | The Young and the Restless | Tyra Hamilton | Regular role |
2009 | The Assistants | Alicia James | Episode: "The Break Up" |
2011 | Let's Stay Together | Raynelle | Episode: "Your Arm's Too Short to Box with Grandparents" |
2012 | Girlfriend Confidential: LA | Herself | Main cast |
2013–15 | Real Husbands of Hollywood | Herself | 4 episodes |
2015–16 | Born Again Virgin | Tara | Main cast |
2017 | Scared Famous | Herself/Contestant | Main cast |
2018–21 | The Real Housewives of Atlanta | Herself | Recurring cast: Season 10; Main cast: Season 11-12; Guest: Season 13 |
2021–present | All the Queen's Men | Marilyn 'Madam' DeVille | Lead role |
2022–2023 | The Real Housewives Ultimate Girls Trip | Herself | Main cast: Season 2 & 4[4] |
Orin orí fọ́nrán
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Song | Artist | Notes |
---|---|---|---|
2006 | "DJ Play a Love Song" | Jamie Foxx | |
2012 | "Best of Me" | Tyrese | |
2013 | "Live It Up" | Jennifer Lopez | |
"J'accélère" | Rohff |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Eva Marcille". Bravo TV Official Site (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-10-01. Retrieved 2022-03-12.
- ↑ "Eva Pigford wins UPN America's Next Top Model". Reality TV world. Retrieved December 26, 2006.
- ↑ "Eva Marcille and Lance Gross Breakup EXCLUSIVE". Essence.com. March 24, 2010. Retrieved November 21, 2015.
- ↑ https://twitter.com/BravoTV/status/1612585672749240335