Daniel Bernoulli
Ìrísí
Daniel Bernoulli | |
---|---|
Daniel Bernoulli | |
Ìbí | 8 February 1700 Groningen, Netherlands |
Aláìsí | 8 March 1782 (aged 82) Basel, Switzerland |
Ibùgbé | unknown |
Ó gbajúmọ̀ fún | Bernoulli's Principle, early Kinetic theory of gases, Thermodynamics |
Religious stance | Calvinist |
Signature |
Daniel Bernoulli (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹjọ oṣù kejì odun 1700, ó sìn di olóògbé ní Ọjọ́ kẹjọ oṣù Kẹta ọdún 1782) jẹ́ ògbóǹtarìgì onímọ̀ Ìṣirò ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Dutch-Swiss mathematician, ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ògbóǹtarìgì onímọ̀ Ìṣirò tí ẹbí Bernoulli.[1] [2]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Swiss mathematician". Encyclopedia Britannica. Retrieved 2019-12-16.
- ↑ "Daniel Bernoulli". Encyclopedia.com. 2019-12-10. Retrieved 2019-12-16.