Chrisland University
Ìrísí
Chrisland University | |
---|---|
Motto | Intellectual Radiance |
Established | 2015 |
Type | Aládani (private) |
Chancellor | W. A. Awosika |
Vice-Chancellor | Chinedum Peace Babalola |
Location | Abeokuta, Ogun State, Nigeria |
Website | chrislanduniversity.edu.ng/Site/ |
Chrisland University wà ní Abéòkúta, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà. Wón dá sílẹ̀ ní ọdún 2015, àti pé National Universities Commission ti fọwọ́sí.[1][2][3]
Ìtàn ìdásílè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọjọ́ kẹtàdínlogún oṣù kẹsàn-án, ọdún 2015, National Universities Commission (NUC) ti Federal Republic of Nigeria fún ilé-ẹ̀kọ́ náà ní àṣẹ pátápátá láti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí ilé-ẹ̀kọ́ aládani ní Nàìjíríà níbẹ̀ kó bẹ̀rẹ̀ ní ọdún 2019.[4]
Àwọn ẹ̀ka
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ẹ̀ka Management and Social Sciences
- English
- Mass Communication
- Economics
- Business Administration
- Accounting
- International Relations and Diplomacy
- Criminology and Security Studies
- Political Science
- Psychology
- Banking & Finance
Ẹ̀ka Natural and Applied Sciences
- Computer Science
- Software Engineering
- Physics with electronics
- Microbiology
- Biochemistry
- Cybersecurity
- Industrial chemistry
- Statistics
- Molecular Biology and Biotechnology
- Industrial mathematics
Ẹ̀ka College of Basic Medical Sciences
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Nursing
- Physiotherapy
- Public Health
- Medical Laboratory Science
Ẹ̀ka College of Law
Law
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Nigeria’s 59 private universities …locations, Vice Chancellors names, websites, dates of establishment". Kukogho Iruesiri Samson. pulse.ng. 22 April 2015. Retrieved 22 November 2015.
- ↑ "Private Universities". National Universities Commission. Retrieved 22 November 2015.
- ↑ "FG gives licences to 9 new private universities". LAIDE AKINBOADE-ORIERE. Vanguard (Nigeria). 5 March 2015. Retrieved 22 November 2015.
- ↑ "Chrisland University". chrislanduniversity.edu.ng. Retrieved 2023-09-15.