Carbamoyl phosphate
Ìrísí
Àdàkọ:Chembox KEGGÀdàkọ:Chembox MeSHName
Carbamoyl phosphate | |
---|---|
(Carbamoyloxy)phosphonic acid | |
Identifiers | |
CAS number | 590-55-6 |
PubChem | 278 |
ChEBI | CHEBI:17672 |
SMILES | C(=O)(N)OP(=O)(O)O
|
InChI | 1S/CH4NO5P/c2-1(3)7-8(4,5)6/h(H2,2,3)(H2,4,5,6)
|
InChI key | FFQKYPRQEYGKAF-UHFFFAOYSA-N |
ChemSpider ID | 272 |
Properties | |
Molecular formula | CH2NO5P2− |
Molar mass | 141.020 g/mol |
Àdàkọ:Cross(what is this?) (verify) Except where noted otherwise, data are given for materials in their standard state (at 25 °C, 100 kPa) | |
Infobox references |
Carbamoyl phosphate jẹ́ kẹ́míkà tí ó lágbára tí ó sì wúlò ní ìbáṣepọ̀ kẹ́míkà nínú ara. Ní àwọn ẹranko tó ń gbé inú ilẹ, ó wà lágbede méjì ní ìyọ nitrogen kúrò nínú ara látàrí Ìyípo urea ìṣètò pyrimidines.
Ìṣètò rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n máa ń ṣètò rẹ latí inú bicarbonate, ammonia (tí a yọ kúrò nínú glutamine), àti phosphate (láti ATP). Enzyme carbamoyl phosphate synthetase, máa ń jẹ́ kó ṣeṣe báyì :
- HCO3− ATP → ADP HO–C(O)–OPO2−3 (carboxyl phosphate)
- HO–C(O)–OPO2−3 NH3 OH− → HPO2−4 −O–C(O)NH2 H2O
- −O–C(O)NH2 ATP → ADP H2NC(O)OPO2−3
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Nelson, David L.; Cox, Michael M. Lehninger Principles of Biochemistry fourth edition. New York: W. H. Freeman and company. [<span title="Please supply an "|ISBN=" of publication, or use "|ISBN= unspecified" for intentional omission.">ISBN missing]