Adeleke Mamora
Ìrísí
Adeleke Olurunnimbe Mamora | |
---|---|
Minister of State for Health | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 23 August 2019 | |
Speaker of the 4th Lagos State House of Assembly | |
In office 2 June 1999 – 30 May 2003 | |
Deputy | Adetoun Adediran |
Asíwájú | Shakirudeen Kinyomi |
Arọ́pò | Jokotola Pelumi |
Senator for Lagos East | |
In office 29 May 2007 – 6 June 2011 | |
Asíwájú | Adeseye Ogunlewe |
Arọ́pò | Gbenga Bareehu Ashafa |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 16 Oṣù Kejì 1953 Lagos State, Nigeria |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressives Congress |
Adeleke Olurunnimbe Mamora tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kejì ọdún 1953 (16 February 1953) jẹ́ gbajúmọ̀ olóṣèlú àti Mínísítà kékeré fún ètò ìlera lọ́wọ́lọ́wọ́ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó ti fi ìgbà kan jẹ́ Agbẹnusọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin tí Ìpínlẹ̀ Èkó lọ́dún 1999, bẹ́ẹ̀ náà wọ́n dìbò yàn án gẹ́gẹ́ bí Sẹ́nétọ̀ lọ́dún 2007, láti ṣojú lábẹ́ àsíyá ẹgbẹ́ òṣèlú Action Congress. [1] [1]In 2003 he was appointed chairman of the Senate Committee on Ethics, Privileges and Public Petitions.[2] [3]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 "Sen. Adeleke Olurunnimbe Mamora". National Assembly of Nigeria. Archived from the original on 2016-03-03. Retrieved 2010-06-14. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ SEBASTINE HON (2003-10-14). "Senate Bribery Allegations: Who Lied?". ThisDay. Archived from the original on 2005-11-25. Retrieved 2010-06-14. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "An Improved Senate, But Some Uninspiring Senators...". ThisDay. 24 May 2009. Retrieved 2010-06-14.