Jump to content

Ìrun wítìrí

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ìrun wítìrí ninu ẹ̀sìn Islam jẹ́ ẹ̀ka kán nínú àwọn èlé ìrun (Nafila), ó jẹ́ ìrun kán tì a ma n kí ní alaalẹ́, lẹ́yìn ìrun Ishai. Àtí pé ó jẹ́ ìrun ẹyọ̀ọ̀kan tí afí n parí ìrun ojúmọ́, lẹ́yìn Shafuhi. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn Suhhan tí ó pọn dandan, tí àwọn Onímọ̀ nínú ẹ̀sìn Islam fọwọ́ sí. Ìrun wítìrí ni ó gbọ́dọ̀ kẹ́yìn gbogbo ìrun ojúmọ́ ní alaalẹ́. [1]

[2]

[3] .

  1. "How To Pray Witr prayer And Importance Of Witr Prayer In Islam Video". Islamreligionguardian. 2017-08-08. Retrieved 2019-12-14. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  2. أخرجه مسلم في كتاب صلاة المسافرين وقصرها- باب صلاة الليل وعدد ركعات النبي " في الليل وأن الوتر ركعة وأن الركعة صلاة صحيحة برقم (737).
  3. أخرجه النسائي في كتاب قيام الليل وتطوع النهار- باب كيف الوتر بخمس ... برقم (1715) وصححه الألباني.