Jump to content

agbẹgilere

From Wiktionary, the free dictionary

Yoruba

[edit]
Agbẹ́gilére

Etymology

[edit]

From a- (agent prefix)gbẹ́ (to carve)igi (wood) (adverbial preposition)ère (sculpture), literally one who carves wood into sculpture.

Pronunciation

[edit]
  • IPA(key): /ā.ɡ͡bɛ́.ɡī.lé.ɾē/

Noun

[edit]

agbẹ́gilére

  1. woodcarver
    Synonyms: agbẹ́gi, (epithet) àkókó
    • 2022 May 14 (last accessed), “Bísí Fákẹ́yẹ”, in John Randle Centre For Yoruba Culture & History[1], archived from the original on 5 July 2022:
      Bísí Fakẹ́yẹ jẹ́ ìlúmọ̀ọ́ká agbẹ́gilére, ó wá láti ìdílé agbẹ́gilére tí ó gbajúmọ̀. Bàbá-bàbá-bàbá rẹ̀ ni agbẹ́gilére Ọláwọyin láti Ìlá Ọ̀ràngún. Ìbátan Lámìdí Fákẹ́yẹ ni ó jẹ́. Àwọn ẹbí Fákẹ́yẹ ti gbé àwọn ìṣe àdáyébá ère gbígbẹ́ ilẹ̀ Yorùbá ga, wọn sì ti sọ ìṣe náà ti gbajúgba dé òkè òkun.
      Bisi Fakeye is a carver of renown, from a family of famous carvers. His great grandfather was the carver Olawoyin from Ila Orangun. He is cousin to Lamidi Fakeye. The Fakeye family have maintained and developed the carving traditions of the Yoruba people and given them international fame.