Norwegian Nynorsk

edit

Noun

edit

gaasi f

  1. obsolete typography of gåsi

Yoruba

edit

Etymology

edit

From English gas.

Pronunciation

edit

Noun

edit

gáàsì

  1. (chemistry) gas
    ipò gáàsìgaseous phase
    gáàsì olórópoisonous gas
    • 2023, Arojinle, 0:08–0:44 from the start, in "Balloon Gas" inhalation is dangerous[1]:
      Ẹ súnmọ́ mi ńbí, gbogbo ẹ̀yin idán onífèrè. Ǹjẹ́ ẹ tiẹ̀ mọ gáàsì tẹ́ ẹ máa ń fi sínú fèrè kó tó di wá di pé ẹ ń gbé e fúnra yín tẹ́ ẹ wá ń fà á símú kákàkiri?
      Come close, all you ballon gas inhailers. Do you even know the gas you put inside the balloons before you now come and be inhaling it everywhere?
  2. natural gas; fuel gas
    • 2022, “Ohùn-kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́: Ìlọ́wọ́sí àwọn ìlú apá Ìwọ̀-Oòrùn nínú ìkógunjàlú tí Russia gbé ko Ukraine”, in Global Voices ní-Yorùbá[2]:
      Wọ́n sọ wí pé púpọ̀ nínú àwọn orílẹ̀-èdè Yúróòpù ló ń gbe ìṣèjọba Russia lọ́wọ́ nípasẹ̀ ríra epo àti gáàsì Russia.
      They argue that multiple European countries have been enabling the Russian regime by buying Russian oil and gas.

Derived terms

edit